Wọ́n sunkún wí pé, “Háà! Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, èéṣe tí nǹkan yìí fi ṣẹlẹ̀ sí Ísírẹ́lì? Èéṣe tí ẹ̀yà kan yóò fi run nínú Ísírẹ́lì lónìí?”