Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 21:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, kò sí ọba ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì; olúkúlùkù sì ń ṣe bí ó ti tọ́ ní ojú ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 21

Wo Onídájọ́ 21:25 ni o tọ