Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 21:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa kò le fi àwọn ọmọbìnrin wa fún wọn ní aya, nítorí tí àwa ọmọ Ísírẹ́lì ti ṣe ìbúra yìí pé: ‘Ègún ni fún ẹnikẹ́ni tí ó fi aya fún ẹnikẹ́ni nínú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì.’ ”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 21

Wo Onídájọ́ 21:18 ni o tọ