Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ bá àwọn ènìyàn ilẹ̀ yí dá májẹ̀mú àlàáfíà, ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò wó pẹpẹ ibi ìsin òrìṣà wọn lulẹ̀.’ Ṣíbẹ̀ ẹ̀yin ṣe àìgbọ́ràn sími. Èéṣe tí ẹ̀yin fi ṣe èyí?

Ka pipe ipin Onídájọ́ 2

Wo Onídájọ́ 2:2 ni o tọ