Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbẹ̀yìn, gbogbo ìran náà sì kú; àwọn ìran tí ó tẹ̀lé wọn kò sì sin Olúwa nítorí wọn kò mọ Olúwa bẹ́ẹ̀ ni wọn kò mọ ohun tí Olúwa ṣe fún Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 2

Wo Onídájọ́ 2:10 ni o tọ