Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 19:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ẹni tí ó rí i sì wí pé, “A kò ti rí i, bẹ́ẹ̀ a kò tí ì ṣe irú nǹkan yìí rí, kì í ṣe láti ọjọ́ tí Ísírẹ́lì ti jáde tí Éjíbítì wá títí di òní olónìí. Ẹrò ó wò, ẹ gbìmọ̀ràn kí ẹ sọ fún wa ohun tí a ó ò ṣe!”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:30 ni o tọ