Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 19:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo kí ọ kú ààbọ̀ sí ilé mi,” ni ìdáhùn ọkùnrin arúgbó náà. “Èmi yóò pèṣè gbogbo ohun tí o nílò, kìkì pé kí ìwọ má ṣe sun ìta.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:20 ni o tọ