Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 19:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n yípadà wọ́n lọ sí inú ìlú náà láti wọ̀ ṣíbẹ̀ ní òru náà, wọ́n lọ wọ́n sì jókòó níbi gbọ̀ngàn ìlú náà, ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó gbà wọ́n sínú ilé rẹ̀ láti wọ̀ sí.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:15 ni o tọ