Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 18:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n súnmọ́ tòsí ilé e Míkà, wọ́n dá ohùn ọ̀dọ́mọkùnrin Léfì náà mọ̀, torí náà wọ́n yípadà, wọ́n sì wọ inú ilé náà lọ wọ́n sì bi í pé, “Tá ni ó mú ọ wa sí ibi? Kí ni ìwọ ń ṣe níhìnìnyìí? Èéṣe tí o fi wà ní ibí?”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 18

Wo Onídájọ́ 18:3 ni o tọ