Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 18:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sì sí ẹnikẹ́ni tí yóò gbà wọ́n sílẹ̀ nítorí pé ibi tí wọ́n ń gbé jìnà sí àwọn ará Ṣídónì, wọn kò sì ní àṣepọ̀ pẹ̀lú ẹnikẹ́ni. Ìlú náà wà ní inú àfonífojì lẹ́bá a Bẹti-Réhóbù.Àwọn ará Dánì sì tún ìlú náà kọ́, wọ́n sì ń gbé inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 18

Wo Onídájọ́ 18:28 ni o tọ