Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 17:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

sọ fún ìyá rẹ̀ pé, “Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀fà ṣékélì fàdákà èyí tótó kílógírámù mẹ́talá tí wọ́n jí mọ́ ọ lọ́wọ́, àti nípa èyí tí mo gbọ́ tí ìwọ ń ṣépè (gégùn ún). Kíyèsi fàdákà náà wà ní ọ̀dọ̀ mi, èmi ni mo kó o.”Nígbà náà ni ìyá rẹ̀ dáhùn pé, “Kí Olúwa bùkún ọ ọmọ mi!”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 17

Wo Onídájọ́ 17:2 ni o tọ