Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 16:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúsónì sì wí pé, “Jẹ́ kí èmi kú pẹ̀lú àwọn Fílístínì!” Òun sì fi agbára ńlá tì wọ́n, bẹ́ẹ̀ ni ilé náà wó lu àwọn ìjòyè àti gbogbo àwọn tí ó wà nínú rẹ̀. Báyìí ni ó pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ nígbà ikú rẹ̀ ju ìgbà ayé rẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 16

Wo Onídájọ́ 16:30 ni o tọ