Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 16:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúsónì sọ fún àwọn ìránṣẹ́ tí ó di ọwọ́ rẹ̀ mú pé, “Ẹ fi mí si ibi tí ọwọ́ mi yóò ti le tó àwọn òpó tí ó gbé tẹ́ḿpìlì dúró mú, kí èmi lè fẹ̀yìn tì wọ́n.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 16

Wo Onídájọ́ 16:26 ni o tọ