Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dẹ̀lílà sì mú àwọn okùn túntún, ó fi wọ́n dì í. Nígbà tí àwọn ọkùnrin Fílístínì ti fi ara pamọ́ sínú yàrá, òun kígbe sí i pé, “Sámúsónì àwọn Fílístínì dé láti mú ọ,” òun sì já okùn náà kúrò ní ọwọ́ rẹ̀ bí òwú.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 16

Wo Onídájọ́ 16:12 ni o tọ