Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kọ lù wọ́n pẹ̀lú ìbínú àti agbára ńlá, ó sì pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú wọn. Lẹ́yìn náà ni ó lọ, ó sì dúró nínú ihò àpáta kan nínú àpáta Étamù.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 15

Wo Onídájọ́ 15:8 ni o tọ