Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Ọlọ́run la kòtò ìṣun omi tí ó wà ní Léhì, omi sì tú jáde láti inú rẹ̀. Nígbà tí Sámúsónì mú mi tan, agbára rẹ̀ sì padà, ọkàn sì sọjí, fún ìdí èyí wọ́n pe ìṣun omi náà ni. Ẹni Hákkò rẹ (oríṣun ẹni tí ó pe Ọlọ́run) èyí tí ó sì wà ní Léhì di òní.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 15

Wo Onídájọ́ 15:19 ni o tọ