Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwá gbà,” ni ìdáhùn wọn. “Àwa yóò kàn dè ọ́, awa yóò sì fi ọ́ lé wọn lọ́wọ́, àwa kì yóò pa ọ́.” Wọ́n sì dé pẹ̀lú okùn túntún méjì, wọ́n sì mú u jáde wá láti ihò àpáta náà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 15

Wo Onídájọ́ 15:13 ni o tọ