Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 15:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ní àkókò ìkórè jéró Sámúsónì mú ọ̀dọ́ ewúrẹ́ kan láti bẹ ìyàwó rẹ̀ wò. Ó ní, “Èmi yóò wọ yàrá ìyàwó mi lọ.” Ṣùgbọ́n baba rẹ̀ kò gbà á láàyè láti wọlé.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 15

Wo Onídájọ́ 15:1 ni o tọ