Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 14:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dáhùn pé,“Láti inú ọ̀jẹun ni ohun jíjẹ ti jáde wá;láti inú alágbára ni ohun dídùn ti jáde wá.”Ṣùgbọ́n fún odidi ọjọ́ mẹ́ta ni wọn kò fi rí ìtúmọ̀ sí àlọ́ náà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 14

Wo Onídájọ́ 14:14 ni o tọ