Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 14:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Baba rẹ̀ sì sọ̀kalẹ̀ lọ láti kí obìnrin náà. Sámúsónì sì ṣe àṣè gẹ́gẹ́ bí àṣà ọkọ ìyàwó ní àkókò náà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 14

Wo Onídájọ́ 14:10 ni o tọ