Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 13:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì Olúwa fara han obìnrin náà, ó sì wí fún un pé, “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ yàgàn, ìwọ kò sì tíì bímọ, ìwọ yóò lóyún, ìwọ yóò sì bí ọmọkùnrin kan.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 13

Wo Onídájọ́ 13:3 ni o tọ