Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì Olúwa náà dá Mánóà lóhùn pé, “Bí ẹ̀yin tilẹ̀ dá mi dúró, Èmi kì yóò jẹ ọ̀kankan nínú oúnjẹ tí ẹyin yóò pèṣè. Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yin bá fẹ́ ẹ pèṣè ọrẹ ẹbọ ṣíṣun, kí ẹ sì fi rúbọ sí Olúwa.” (Mánóà kò mọ̀ pé ańgẹ́lì Olúwa ní i ṣe.)

Ka pipe ipin Onídájọ́ 13

Wo Onídájọ́ 13:16 ni o tọ