Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kò gbọdọ̀ jẹ ohunkóhun tí ó bá ti inú èṣo àjàrà jáde wá, bẹ́ẹ̀ ni kò gbọdọ̀ mu wáìnì tàbí àwọn ọtí líle mìíràn tàbí jẹ ohunkóhun tí ó bá jẹ́ aláìmọ́. Ó ní láti ṣe ohun gbogbo tí mo ti pa láṣẹ fún un.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 13

Wo Onídájọ́ 13:14 ni o tọ