Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́fítà sì dáhùn pé, “Ṣé kì í ṣe pé ẹ kóríra mi tí ẹ sì lé mi kúrò ní ilé baba mi? Kí ló dé tí ẹ fi tọ̀ mí wá báyìí nígbà tí ẹ wà nínú wàhálà?”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:7 ni o tọ