Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 11:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà tí ó rí i ó fa aṣọ rẹ̀ ya ní ìbànújẹ́, ó sì ké wí pé, “Háà! Ọ̀dọ́mọbìnrin mi, ìwọ fún mi ní ìbànújẹ́ ọkàn ìwọ sì rẹ̀ mí sílẹ̀ gidigidi, nítorí pé èmi ti ya ẹnu mi sí Olúwa ní ẹ̀jẹ́, èmi kò sì le ṣẹ́ ẹ̀jẹ́ mi.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:35 ni o tọ