Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 11:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀mí Olúwa sì bà lé Jẹ́fítà òun sì la Gílíádì àti Mánásè kọjá. Ó la Mísípà àti Gílíádì kọja láti ibẹ̀, ó tẹ̀ṣíwájú láti bá àwọn ará Ámónì jà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:29 ni o tọ