Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 11:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọ́n rin ihà kọjá, wọ́n pẹ́ àwọn ilẹ̀ Édómù àti ti Móábù sílẹ̀, nígbà tí wọ́n gba apá ìlà oòrùn Móábù, wọ́n sì tẹ̀dó sí apá kejì Ánónì. Wọn kò wọ ilẹ̀ Móábù, nítorí pé ààlà rẹ̀ ni Ánónì wà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:18 ni o tọ