Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba àwọn Ámónì dá àwọn oníṣẹ́ Jẹ́fità lóhùn pé, “Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde ti Éjíbítì wá. Wọ́n gba ilẹ̀ mi láti Ánónì dé Jábókù, àní dé Jọ́dánì, nítorí náà dá wọn padà lọ ní àlàáfíà àti ní pẹ̀lẹ́ kùtù.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:13 ni o tọ