Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 1:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará Ámórì ti pinnu láti dúró lórí òkè Hérésì àti òkè Áíjálónì àti ti Ṣáíbímù, ṣùgbọ́n nígbà tí ẹ̀yà Jósẹ́fù di alágbára wọ́n borí Ámórì wọ́n sì mú wọn sìn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:35 ni o tọ