Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 1:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹ̀yà Ṣébúlúnì náà kò lé àwọn ará Kítírónì tàbí àwọn ará Nẹ́hálólì ṣùgbọ́n wọ́n sọ wọ́n di ẹrú. Wọ́n sì ń sin àwọn ará Ṣébúlúnì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:30 ni o tọ