Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà sí lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Hítì, ó sì tẹ ìlú kan dó, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Lúsì èyí sì ni orúkọ rẹ̀ títí di òní.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:26 ni o tọ