Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe, àwọn ológun Júdà tẹ̀lé àwọn ológun Ṣíméónì arákùnrin wọn, wọ́n sì lọ bá àwọn ará Kénánì tí ń gbé Ṣéfátì jagun, wọ́n sì run ìlú náà pátapáta, ní báyìí à ò pe ìlú náà ní Hómà (Hómà èyí tí ń jẹ́ ìparun).

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:17 ni o tọ