Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn èyí wọ́n tẹ̀ṣíwájú láti bá àwọn tí ń gbé Débírì jagun (orúkọ Débírì ní ìgbà àtijọ́ ni Kíríátì-Ṣéférì tàbí ìlú àwọn ọ̀mọ̀wé).

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:11 ni o tọ