Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 8:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a ṣe ṣe ọ̀pá fìtílà náà nìyìí: A ṣe é láti ara wúrà lílù: láti ìṣàlẹ̀ títí dé ibi ìtànná rẹ̀. Wọ́n ṣe ọ̀pá fìtílà náà gẹ́gẹ́ bí bátànìi tí Olúwa fi han Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:4 ni o tọ