Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bá Árónì sọ̀rọ̀ kí o wí fún un pé. ‘Nígbà tí ó bá ń to àwọn fìtílà, àwọn fìtílà méjèèje gbọdọ̀ tan ìmọ́lẹ̀ sí àyíká níwájú ọ̀pá fìtílà.’ ”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:2 ni o tọ