Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 7:53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún, tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Élísámà ọmọ Ámíhúdì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:53 ni o tọ