Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 7:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Sélúmíélì ọmọ Surisádáì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:41 ni o tọ