Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n mú ọrẹ wọn wá ṣíwájú Olúwa: kẹ̀kẹ́ ẹrù mẹ́fà ti abo, àti akọ màlúù kan láti ọ̀dọ̀ olórí kọ̀ọ̀kan àti kẹ̀kẹ́ ẹrù kan láti ọ̀dọ̀ olórí méjì. Wọ́n sì kó wọn wá sí iwájú àgọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:3 ni o tọ