Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 6:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Lẹ́yìn tí Násírì bá ti fá irun ìyàsọ́tọ̀ rẹ̀ tan, àlùfáà yóò mú apá àgbò bíbọ̀, àkàrà aláìwú kan àti àkàrà fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tí kò ní ìwúkàrà láti inú apẹ̀rẹ̀ yóò sì kó gbogbo rẹ̀ lé e lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 6

Wo Nọ́ḿbà 6:19 ni o tọ