Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

pẹ̀lú ọrẹ ohun jíjẹ àti ọrẹ ohun mímu, apẹ̀rẹ̀ àkàrà tí a kò fi ìwúkàrà ṣe, àkàrà tí a fi ìyẹ̀fun dáradára pò pọ̀ mọ́ òróró àti àkàrà fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tí a fi òróró sọjọ̀ lé lórí.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 6

Wo Nọ́ḿbà 6:15 ni o tọ