Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbọdọ̀ ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ sí Olúwa fún àkókò ìyàsọ́tọ̀ rẹ̀, ó sì gbọdọ̀ mú akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan wá gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹ̀bi. Kò sì ní í ka àwọn ọjọ́ ìyàsọ́tọ̀ rẹ̀ ti tẹ́lẹ̀ nítorí pé ó tí ba ara rẹ̀ jẹ́ ní àkókò ìyàsọ́tọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 6

Wo Nọ́ḿbà 6:12 ni o tọ