Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbọdọ̀ jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí ó sẹ̀. Ó gbọdọ̀ san ẹ̀san rẹ̀ ní ojú owó, kí ó sì fi ìdámárùn ún rẹ̀ lée, kí ó sì fi fún ẹni tí Òun jẹ̀bi rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 5

Wo Nọ́ḿbà 5:7 ni o tọ