Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Irú ẹni bẹ́ẹ̀ yálà ọkùnrin tàbí obìnrin, ẹ lé wọn jáde kúrò nínú ibùdó kí wọn má báà ba ibùdó wọn jẹ́ níbi tí èmi ń gbé láàrin wọn”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 5

Wo Nọ́ḿbà 5:3 ni o tọ