Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 5:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlùfáà yóò sì mú kí obìnrin náà mu omi kíkorò tí ń mú ègún wá yìí, omi náà yóò wọ inú rẹ̀ yóò sì fa ìrora kíkorò fún obìnrin náà bí ó bá jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 5

Wo Nọ́ḿbà 5:24 ni o tọ