Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 35:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí a fi ẹ̀sùn kàn gbọdọ̀ dúró nínú ìlú ìsásí títí di ìgbà tí olórí àlùfáà bá kú; lẹ́yìn ikú olórí àlùfáà, ni ó tó lè padà sí ibi tí dúkìá rẹ̀ wà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 35

Wo Nọ́ḿbà 35:28 ni o tọ