Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 35:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpèjọ gbọ́dọ̀ dá ààbò bo ẹni tí a fi ẹ̀sùn ìpànìyàn kàn, kí a sì ran-an padà lọ sí ìlú ìsásí tí ó ti wá. Ó gbúdọ̀ dúró níbẹ̀ títí di ìgbà tí olórí àlùfáà bá kú, ẹni tí a fi àmì òróró yàn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 35

Wo Nọ́ḿbà 35:25 ni o tọ