Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 33:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa àsẹ Olúwa, Árónì àlùfáà gùn orí òkè Hórì, níbẹ̀ ni ó kú. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kárun, ọdún ogójì, lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti ilẹ̀ Éjíbítì jáde wá.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 33

Wo Nọ́ḿbà 33:38 ni o tọ