Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 33:24-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Wọ́n kúrò lórí òkè Ṣéférì wọ́n sì págọ́ ní Hárádà.

25. Wọ́n kúrò ní Hárádà wọ́n sì pàgọ́ ní Mákélótì.

26. Wọ́n kúrò ní Mákélótì wọ́n sì pàgọ́ ní Táhátì.

27. Wọ́n kúrò ní Táhátì wọ́n sì pàgọ́ ní Térà.

28. Wọ́n kúrò ní Térà wọ́n sì pàgọ́ ní Mítíkà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 33