Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 32:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yin bá kọ̀ láti ṣe èyí, ẹ̀yin yóò máa dẹ́ṣẹ̀ sí Olúwa; kí ẹ̀yin kí ó sì mọ̀ dájú pé ẹ̀ṣẹ̀ yín yóò fi yín hàn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 32

Wo Nọ́ḿbà 32:23 ni o tọ