Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 32:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Nítorí wọn kò tẹ̀lé mi tọkàntọkàn, kì í ṣe ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin náà tí ó jẹ́ ogún ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ tí ó gòkè láti Éjíbítì ni yóò rí ilẹ̀ tí mo pinnu gẹ́gẹ́ bí ìbúra fún Ábúráhámù, fún Ísáákì àti fún Jákọ́bù:

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 32

Wo Nọ́ḿbà 32:11 ni o tọ